Lyrics for Iranlowo By Bukola Bekes
[Verse 1]
Emi o gbe oju mi sori oke ran ni
Ibo ni Iranlowo mi yo wa ti wa
Iranlowo mi yo to do Oluwa wa
Ti o da orun oun aye
[Chorus]
Iranlowo mi
Lati odo re ni
Oba to da orun aye
Ran mi lowo Oluwa
Ran mi lowo
[Verse 2]
Oun ki yio je ki ese mi koye
Eniti n pamimo
Kiitogbe beeni kii sun rara o
E no dey sleep o
[Chorus]
Iranlowo mi
Lati odo re ni
Oba to da orun aye
Ran mi lowo Oluwa
Ran mi lowo
Iranlowo mi
Lati odo re ni
Oba to da orun aye
Ran mi lowo Oluwa
Ran mi lowo
[Chorus]
Iranlowo mi
Lati odo re ni
Oba to da orun aye
Ran mi lowo Oluwa
Ran mi lowo
Ran mi lowo
Ran mi lowo
Ran mi lowo
Other Bukola Bekes Lyrics
- Bukola Bekes – Olori Kokoro Lyrics
- Bukola Bekes – You Are Good Lyrics
- Bukola Bekes – Gbangba Gbangba Lyrics
- Dare David – Awesome God Ft. Bukola Bekes Lyrics
- Bukola Bekes – Thank You Jesus Lyrics
- Bukola Bekes – Thank You Jesus Lyrics
- Mercy Idegwu Ft. Bukola Bekes – Iyanu Lyrics
- Bukola Bekes – Halleluyah Lyrics