Site icon GMLyrics

Ajibola Mabel Aina – Olorun Ayo Lyrics

Ajibola Mabel Aina Olorun Ayo Lyrics

Lyrics for Olorun Ayo By Ajibola Mabel Aina

Olorun agbaye ooo momope mi wa oo
Gbongbo idile Jesse oo gbanigbani lojo isoro
Olorun ayo mo de oo momope mi wa
Oba adagba matepa
adani magbagbe eni
Eseun oo olorun mi
Ese eledumare
Morojo oni lalafia oo
Olorun ayo gbope mi

Oba mimo ye gbope mi
Olorun ayo gbope mi
Oba mimo ye gbope mi
Olorun ayo gbope mi
Ayeraye ninu awon orun gbope mi
Olorun ayo gbope mi
gbongbo idile Jesse ee
Olorun ayo gbope mi

Ope ye oo baba
Ope ye oo Olorun ife
Ife re laye mi po oo
Ife ti ko labawon

Ife re ninu aye mi opo
Ayeraye ninu awon orun
Orogojigo Olorun imisi
Eseun oluwa

Nigba todab’otitan Olorun dide funmi
Nigba to dab’okudie oo baba gbogo re yo
Oba adani masiregun lolorun timo gboju le
Botiwu kiji leja to konije ko gbemi lo

Baba mimo ye gbope mi
Olorun ayo gbope mi
Elshaddai gbope mi oo
Olorun ayo gbope mi
Mimo mimo Eledumare
Olorun ayo gbope mi
Orogojigo Olorun imisi
Olorun ayo gbope mi
Oba lana oba loni oba titi ayeraye
Olorun ayo gbope mi
Gbongbo idile Jesse oo
Olorun ayo gbope mi
Afunnimasiregun
Olorun ayo gbope mi
Abanise gbope mi oo
Olorun ayo gbope mi

Exit mobile version