Site icon GMLyrics

Adeoye Otemuyiwa Adanimagbagbe – Maritemise Lyrics

Adeoye Otemuyiwa Adanimagbagbe Maritemise Lyrics

Lyrics for Maritemise By Adeoye Otemuyiwa Adanimagbagbe

Intro:

Chorus: Bo ti wu ki ilu le to Maritemise o
Backup: Repeat Chorus
/3×
(Adlip)
Lead repeat call: Bo ti wu ki ilu le to maritemise
Backup: Repeat Chorus

Lead Vocal: Ire owo ire Omo, aiku bale Oro
Baxkup: Repeat chorus
L/v: Bo ti wu ki naija le to maritemise Baba Backup repeat chorus
L/v: Oluwa nbe leyin mi o
Jehovah nbe leyin mi o
Adanimagbagbe nbe leyin mi o
Jehovah nbe leyin mi, Ajinde ati iye
O’nbe leyin mi, Bo ti ki ilu le to
Maritemise ooo
Backup: Repeat chorus

L/V: Ninu Odun yi ire gbogbo ko wo le mi ri o
Backup: Repeat Chorus
Lead: ilu le ile Cole maritemise o….Backup: Repeat Chorus

Syncopation( insteumental)

Backups: Maritemise /2× Bo ti le wu kilu le to Maritemise//2×

L/v: Ahh! Majemu re ni mo diro mo ileri re ni mo gbekele ooo/2× Eni gbekele loluwa ko ni jogun ofo, bo ti wu kilu leto Maritemise oo
Backups: Repaeat Chorus
L/v: Repeat Chorus
Backup: Repeat Chorus
Call: Ni nàijiria ni Oke okun Maritemise oo odidaadan — Backup: Repeat chorus
L/v: Bo ti wu ki ilu leto Maritemise

Adliping: (Marona gbegba laye)

Bridge:

L/v: Ma fowo gbeyin leyin mi o/2×
Owo,se koko kosemani//2×
Bo ti wu ki ilu le to Maritemise ooo—-All: Repeat Chorus
L/V: ire gbogbo ko wo ile mi wa
Ki n’lowo lowo ki nribatise Baba oo Baxkups: Repeat chorus

Bridge:
Lead: Iyanu asele…….Backups: Odamiloju
Iyanu t’oju ari…. ” ”
Iyanu t’eti agbo.. ” ”
Iyanu t’enu aso..” ”
Asele n’ile mi ….” ”
Asele nile gbogbo wa….” ”
Iyanu ko wa mi ri …….” ”
Iyanu asele eee

Other Adeoye Otemuyiwa Adanimagbagbe Lyrics
[display-posts category=”Adeoye Otemuyiwa Adanimagbagbe” exclude_current=”true”]

Exit mobile version