Skip to content
Home » Adejumoke Dada » Adejumoke Dada – Alagbada Ina Lyrics

Adejumoke Dada – Alagbada Ina Lyrics

    Lyrics for Alagbada Ina By Adejumoke Dada

    Alagbada ina alawotele orun,
    Oba nla  alara gbayida o ,
    Eni kerin ninu ina ileru,ina nla ton joo igbe oo,
    Ti igbe o si runn.

    Otun ni o, olorun aji dara,
    Otun Len deru aye eda gbogbo,
    Lotun lotun Len shi ilekun ojo gbogbo,
    Aji dara fi aye mi da ara ire.

    Bawo wo lo sheje ti omi fi de inu agbon?
    Ona wo lo gbegba ti iji ole da omi inu agbon nu,
    Iyan eti okun ta lo le ka won,
    Gbogbo omi   inu okun mo ni how many liters ni gan?

    Be sini omi n be lorun,o gbe gbogbo aye so ri ikun omi,
    oda ile osi
    Tun da awon oke,
    Aji dara iwo la lara gbayida oo.

    Ina nla to pin okun niya,
    Ina nla to wo odi jeriko,
    Ina nla ti o te ogun ayemi riiii,
    Ina nla ton joo igbe o,
    Ti igbe osi runn.

    Oba ha 4x
    Oba ha 5x
    Oba ha 4x
    Oba haaa iyanu ni ooo..

    Other Adejumoke Dada Lyrics
    [display-posts category=”Adejumoke Dada” exclude_current=”true”]

    Leave a Reply

    Your email address will not be published. Required fields are marked *