Skip to content
Home » Adejoke Felicia » Adejoke Felicia – Ijoba (Kingdom) Ft. Anointing Oluwaseun Lyrics

Adejoke Felicia – Ijoba (Kingdom) Ft. Anointing Oluwaseun Lyrics

    Lyrics for Ijoba (Kingdom) By Adejoke Felicia Ft. Anointing Oluwaseun

    Chorus:
    Ijoba to so nu
    Ijoba to sonu bawa wa
    Ijoba to Kuna to wa so na afe o
    Eleduwa oba ire abe o gba ko so

    Solo 1:
    On the increase of government oluwa.
    Ninu itesi wa ju ijoba wa oluwa.
    And for peace there will be no end
    alafia koni do pin lailai o
    Eleduwa oba ire abe o gbakoso

    (Back to chorus Ijoba to sonu)

    Aye ti fo ju tipe tipe
    Idamu ba okan wa baba anbe o, are my aye to wa so na afe o
    Eleduwa oba ire abe o gbakoso

    (Back to chorus Ijoba to sonu)
    .

    Solo 3:
    I will seek what was lost
    Gbogbo owu rara to so nu ni ma gba pada
    And bring back what was driven away
    Eleduwa oba ire abe o gbakoso

    (Back to chorus Ijoba to sonu bawa wa)

    Aye ti shina oti pe
    Idamu ba okan wa nbe o
    Ani lo ite si wa ju oluwa to wa Sona
    Idamu ba okan wa nbe o fun atunse
    Ninu iporuru okan lan gbe ni gbogbo igba
    Wa tun aye wa se

    .Aye ti Sina oti pe
    Idamu ba okan wa nbe o fun atunse afi oruko nla re be o
    Dakun gbakoso

    ( Back to chorus Ijoba to sonu)

    Ijoba Yi sisan ba wa da si
    Oni segun nla o
    Ani lo re fun iwo San nla
    Do ki ta to mo ye wa wo wa San
    Sanu… Wa.

    ( Back to ijoba to sonu)

    Other Adejoke Felicia Lyrics [display-posts category=”‌Adejoke Felicia” exclude_current=”true”]

    Leave a Reply

    Your email address will not be published. Required fields are marked *