Lyrics for Ife Eyi Po By Adediran Tolulope
[Chorus]
Ife eyi ma po
Ife to tobi
Ife eyi ma po
Ife o laatoke wa
[Verse]
Kini moje,, Tani mina
Tofi fe mi,, Lapoju Baba o
Kini moje,, Tani mina
Tofi ku funmi ni Kafari
[Chorus]
Ife eyi ma po
Ife to tobi
Ife eyi ma po
Ife o laatoke wa
[Vamp]
Ife ee ooo
Ife o laatoke wa
Ife ti ko labawon o
Ife o laatoke wa
Ife alailegbe oo
Ife o laatoke wa
Me ma riru ife eyi ri o
Ife o laatoke wa
Me ma riru ife eyi ri o
Ife o laatoke wa