Skip to content
Home » A Segun Ati Ajogun Ni A Je (Yoruba Hymns)

A Segun Ati Ajogun Ni A Je (Yoruba Hymns)

  A Segun Ati Ajogun Ni A Je

  1. A segun ati ajogun ni a je,
  Nipa eje Kristi a ni isegun
  B’Oluwa je tiwa, a ki yo subu
  Ko s’ohun to le bori agbara re
  Asegun ni wa, nipa eje Jesu
  Baba fun wa ni ‘segun, nipa eje Jesu
  Eni t’a pa f’elese
  Sibe, O wa, O njoba
  Awa ju asegun lo
  Awa ju asegun lo

  2. A nlo l’oruko Olorun Isreal
  Lati segun ese at’aisododo
  Kise fun wa, sugbon Tire ni iyin
  Fun ‘gbala at’isegun ta f’eje ra

  3. Eni t’O ba si segun li ao fi fun
  Lati je manna to t’orun wa nihin
  L’orun yo sig be imo ‘pe asegun
  Yo wo ‘so funfun, yo si dade wura. Amin

  Other Yoruba Hymns Lyrics
  [display-posts category=”Yoruba Hymns” exclude_current=”true”]

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *