Skip to content
Home » Mega 99 » Mega 99 – Wa Gbo Adura Lyrics

Mega 99 – Wa Gbo Adura Lyrics

  Lyrics : Wa Gbo Adura By Mega 99

  Interlude

  Wa gbo adura mi

  Ba mi se ki n le rogo lo laye

  Chorus: Wa gbo adura mi

  Ba mi se ki n le rogo lo laye

  Wa gbo adura mi oooo

  Ba mi se ki n le rogo lo laye

  Wa gbo adura mi, ba mi se ki n le rogo lo laye (Baba)

  Wa gbo adura mi, ba mi se ki n le rogo lo laye

  Igbe mi ma je o dabi igbe aja niwaju re Olorun mi

  Igbe mi ma o je dabi igbe agutan niwaju re Olorun mi

  Oluwa ma ta mi nu , faanu gba mi

  Se ni ko fami mora ooo

  Oni majemu ayo

  Gbogo mi jade

  Chorus …..

  Se fun mi nigba ti aso si n duro lejika mi Olorun mo be o

  Se funmi nigba ti eyin mi ran egungun

  Olorun mi shaanu mi

  Ma je ki n ti darugbo tan

  Ki ti ma fopa tele

  Ki ogo mi to de oo

  Tête bamise oo

  Ojo ti n lo

  Chorus ….

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *