Skip to content
Home » Lady Evang. Toyin Leshi » Lady Evang. Toyin Leshi – Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon Lyrics

Lady Evang. Toyin Leshi – Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon Lyrics

  Lyrics for Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon By Lady Evang. Toyin Leshi

  Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon
  Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon
  Bi Gbogbo Irun Ori Mi Baje Kiki Ahon

  Ko to lati yin Baba logo

  Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
  Kòtó Kòtó láti yín Bàbá lógo
  Kòtó kòtò láti yín Bàbá lógo
  Kòtó ooo

  Bí gbogbo irun orí miii
  VOCALS: Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n

  Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
  Kòtó Kòtó láti yín Bàbá lógo
  Kòtó kòtò láti yín Bàbá lógo
  Kòtó ooo

  Bí gbogbo irun orí miii
  VOCALS: Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n   Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
  Kòtó Kòtó láti yín Bàbá lógo
  Kòtó kòtò láti yín Bàbá lógo
  Kòtó ooo

  Bí gbogbo irun orí miii
  VOCALS: Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n

  Ona iye ti mo wa yin
  Oluwa wa gbe mi ro
  Ma ja pade seyin
  Jesu wa gbe mi ro

  Ona iye ti mo wa yin
  Jesus wa gbe mi ro
  Ma ja pade seyin
  Jesu wa gbe mi ro

  Ona iye ti mo wa yin
  Jesus wa gbe mi ro
  Ma ja pade seyin
  Jesu wa gbe mi ro

  Ona iye ti mo wa yin
  Jesus wa gbe mi ro
  Ma ja pade seyin
  Jesu wa gbe mi ro

  Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n
  Kòtó Kòtó láti yín Bàbá lógo
  Kòtó kòtò láti yín Bàbá lógo
  Kòtó ooo

  Bí gbogbo irun orí miii
  VOCALS: Bí gbogbo irun orí mi jẹ́ kìkì ahọ́n

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *