Skip to content
Home » Labisi » Labisi – Adara Lyrics

Labisi – Adara Lyrics

  Lyrics for Adara By Labisi

  Idupe nbo idunnu Ade idupe nbo ooo idunnu Ade
  Ajanaku ti segun mi idupe nbo

  Ohun taye fe sohunkol’Olorun mi se idunnu ti de

  Baye Fe baye ko oo Omo Olorun lemi se idupe nbo atileyin mi l’Olorun mi shosho idunnu ti de

  Ekun le Dale sugbon ayo nbo lowuro idupe nbo
  Masokumo maronumo baba nbe leyin re idunnu ti de

  Adara fun mi o
  Lona gbogbo
  Adara fun mi o
  nigbagbogbo emi o ni seyi sokun emi o ni se lasemo gbogbo ohun moba dawole loma yori si rere lase Olorun oba emi o ni seyi sokun emi o ni selasemo gbogbo ohun moba dawole yo ma fogo fun oruko re o

  Adara fun mi o lonagbogbo(lonagbogbo nigbakugba)
  Adara fun mi o lonagbogbo (nigbagbogbo)
  Wa finu soyun wafeyin gbomo pon idupe nbo gbogbo ara ile ara oko niwa ba e dupe Idunnu ti de maronunmo
  Tori oluwa tise fun wa idupe nbo atileyin wa l’Olorun wa shosho idunnu ti de

  Adara fun wa o lonagbogbo (lonagbogbo nibikibi)
  Adara fun wa o lonagbogbo
  Adara fun wa o lonagbogbo (nibikibi)
  Adara fun wa wa o lonagbogbo (Amin).

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *