Skip to content
Home » Clement Whyte » Clement Whyte – Agbara Olorun Po Lyrics

Clement Whyte – Agbara Olorun Po Lyrics

  Lyrics : Agbara Olorun Po By Clement Whyte

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Onisé akabakibiti
  Owun l’ Olorun
  To n’ bé ki aiye to wà
  O la na fun awon omo Israeli
  Ba mi sè ooooohh
  Ki n ba le sè lé ró

  Onisé akabakibiti
  Owun l’ Olorun
  To n’ bé ki aiye to wà
  O la na fun awon omo Israeli
  Ba mi sè ooooohh
  Ki n ba le sè lé ró

  Oooooooo la na fun awon omo Isrealii
  Ba mi sè oohh
  Ki n ba le sè lé ró

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Oba ti a ri
  Ti a mo ododo ré
  Alagbara to n’ gba agbara l’ owo alagbara
  Owun lo l émi ti mo m’ mi
  Owo di Jeriko
  Oba to ran wa lówo ni gba ti Aba si se
  Owun l’ Oba to Joko si ori ité Ni agbala awon eni
  Oba Ala anu
  Oba to pin anu
  O wo di Jericho
  AGBARA OLORUN PO

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  Ola na si ori okun
  Bi oni ja ba l’ owun Oja mó
  O wodi Jericho
  Iwó a l’ o sésé béré ti é

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  Obami alagbara
  Ola na si ori okun
  O wodi Jericho

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Ehhhhhh…
  Baba awon alayi ni baba
  O wo ken bé re ibi ja
  Ala anu l’ eje
  Oba ti n’gbe ni ibi ti akolegbe
  Oba to ma wa nigba ti aye o ni si
  Eeehh

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Agbara Olórun pó
  Agbara Olórun pó
  O la na si ori Okun
  O wo di Jericho

  Woooooooooooo!

  Leave a Reply

  Your email address will not be published. Required fields are marked *